Lirik Lagu Kadara Oriyomi Kehinde

T Reign On The Mix
Lal-amru Amri Wala Taqdiru Teqdiiri
Walal Umuru Lati Tejri Bi TaqdiiriBii Khaalikun, Roziqun Man Sha-a Yaf-alu Bii
Ahato Bi Ilimuhu Min Qobuli Taqdiiri

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Keda To Waye, Ma L′olohun Ti Seto
Ninu Oyun Eda Igba Tonbe Logoji Ojo
Lotiran Malaika Kan, Kon Gbe Kadara E S'orun Fun
Yio Pe Biò Nipe, Yio Pe Biò Nipe

Yio La Ni Biò Nila Gan O, Kadara Kowa, Ilahi Oba Mi Tiko
Teda Ba Ndogbon, Olohun Loni Final Say
Kadara Tigbe, Olohun Lonwo Akoko Eda

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Ba-adal Istiadza Wal-basmala
Wataquu Fitnatan La Tuhzibana Ladzina Zolamu Minkun Khaasotan
Wa-alamu Anna Llaha Shadidul Iqobi

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Seri Teda Ba Nkanju To S′ogun Owo Gan Te O Mope
Ola Tako Mo, Lo Nfikanju Fa Kole Po O
Ola Ojo Ola Re, Ola Ojo Ola Re
Gbogbo E Naa Lonfapo O, Tio Ba Sora
Tiò Ba Sora, Yio Jiya Yio Situn Kan Omo Gan
Nitoriwipe Yio Degun Leyin Toba Ku Tan

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Ninu Oun Gbogbo, Eyi T'olohun Oba Da
Ose Wa Jeti
Eda Adamo Lo Yato O, Kotokoto Aye Ni
Gbogbo Nti Owo O To O
Mafi Gòngò Fa, Lomo Adamo Yio Ma Wi
Toba Wa Jasiparun, Omo Eda A Ma Gekaje Ni

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Seri Kaje Kalemu
Seri Kaje Kalemu, Ti Eda Nfojojumo Wa
Ounje Oòjo, Sebolohun Lomase
Ajoke Aye Ni, Be Gbagbo Be O Ba Gbagbo
Tebi Banpani Lat'owuro Koto Dale
Oba To D′enu Nibūmbu Ase Oun Toma Je

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Eba Maje Ka Kanju Kagba F′olohun Aseda O
Ona Atije, Mio Sope A Ma Ma Wao
Igbiyanju Ni, Mio Sope A Ma Mase O

Sungbon Oun Tio Lodi, Oun Tio Lodi
Si T'olohun Ni O Da, Eyi Tio Tako Ilana Annabi Nio To O
Nibi Tatise, K′olohun O Forijiwa

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Haa Seri Katepa Mose, Kasi F'adua Naa Kun
Katun Ma Toro Gbogbo Nto Wiwa Tafe
Oun Yiowu Ka Toro, Ashiri Bibo Sha Lagba O

Komaseni To Nlani, Koseni To Nlani
Koseni To Nlani, Ayafi Olohun Mi Nikan
Mase Gbekele Elomi, Ilahi Shani Ko Gbojule

Kadara Tigbe, Olohun Lo L,agbega Eda O Mo, Se Leda Nsareka
Onsare Atila, Olohun Nwo Akoko Fun

Olohun Nwo Akoko Fun, Olohun Nwo Akoko Fun
Olohun Nwo Akoko Fun, Olohun Nwo Akoko Fun

Allahu Allah, Yah Hayyu, Yah Qoyyumu
Allahu Allah, Yah Hayyu Yah Qoyyumu
Allahu Allah, Yah Hayyu, Yah Qoyyumu
Allahu Allah, Yah Hayyu Yah
Qoyyumu

Iwo Naa Ni, Lole Seun Nti Eda Nwa O
Iwo Naa Ni, Lole Seun Nti Eda Nwa O
Eni Gbekele Elomiran Leyin Re
Ijakule Ma Lonitoun Nbere
Emi O Nifi Olohun Sile Siun Toda

Allahu Allah, Yah Hayyu, Yah Qoyyumu
Allahu Allah, Yah Hayyu Yah
Qoyyumu

Isilamu Yi O Oo, Isilamu Yi Mio Ni Fisile Laise O
Tori Pongbemi O, Tori Po Ngbemio, Koma Damimole Ri, Tikinikan Base
Mogba Wipe Idanwo Ni, Binpari Idanwo
Binpari Idanwo Igbadun Ni Falala Faalala

Allahu Allah, Yah Hayyu, Yah Qoyyumu
Allahu Allah, Yah Hayyu Yah
Qoyyumu

Kalimo Kan Nbe Toba Wa Ninu Aye Eda O, Abeegbo
Gbolohun Kan Nbe, Toba Wa Ninu Aye Eda
Aye Eda Adun Bi Oyin Wallahi Tallahi
Kalimo Yen, La Ilaha Illa Llahu Nio

Allahu Allah, Yah Hayyu, Yah Qoyyumu
Allahu Allah, Yah Hayyu Yah
Qoyyumu

Toba K′owokan Adan Afi Rogi
Toba K'owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
T′eyan Ba Wa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Toba K'owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
T'eyan Ba Wa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Oba To Dagi Ope Tun Dasofun, Ope Tun Wora E Ola Tun Yika
L′ope Ba Fara E Saraye Loore
Nigi Ope Fiwan Niyi Loju Omo Araye

Toba K′owokan Adan Afi Rogi
Toba K'owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Sebolowo Sha Niwo Bose Lowoto, Owo Towa Nipamo Sole Natan
Atomo Atomo Omo Se Ele Jo Natan, Tiwon Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ootie Niso Pooni Wabere Oro

Owe Sonbi Sorin Meja Loma Npa, Oro Tio Ba′kungbe Loma Tun Jabo
Lonso Sawon Alaini Tonbere Ore
Igi Ope Tunwa Sanfani Ju Iwo Lo

Toba K'owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Sebolola Sha Niwo Bose Lola To, Gbogbo Dukia Aye Shaloni Pata
Tokunrin Bawa Sodo E Tonbere Ore, Wa So Funwon Pooni Bose Lolato

Oro Pon O Wulo Fun E Lomanso
Sungbon Toba J′obinrin Lotoe Wa
Wa S'owo Di Mario Nibi Loma Daku Si

Toba K′owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Iwo Tojeoe Erū Lofi K'olajo, Lonibara Basi Tewo O Sope What?
Pe"oro Lapa Lese Kini O Lo Wase Fun?
Botun Reni Tio Dape Wa Tun Riwi

Olel'oju Won O Fo Pe Se Non Ndogbon
Ese Towa Lorun E Acre Kan Ni
Boomo Tele Se Ore O Je Lo Tūba

Toba K′owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Innama Sodaqotu Lil-fuqorai
Wal-masakini Wal-amiliina Alayha
Wal-muwallafati Qulubuhum
Wafi Riqobi Wal-garimina
Wafi Sebili Llahi Wabni Sebili
Faridotan Mina Llahi, Wallahu Aleemun Akimun Atore

Toba K′owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Alfuqorau T'olohun Minso, Al-masakinu T′olohun Minwi
Kiise Pawon Ton O Pe Lonsoro Won
Bonpe Lara Bon ò Pe Tore Lonwi
Boosi Lowo Lapo Tio Lefi Tore

Kosoro Sadaka Gan To Loro Enu
Soro Tutu Tosida Tole Moriwu
Mawo Towo Tiosi Toofi Tore
Kan Sadua Falaini Kogba Laada

Toba K'owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Olowolayemo Tiyin Nmotun Riri
Eyin O Tore Nibi Teyan O Si Afi Kojupe
Kojupe Kero Tunpo Konle Kan Saara
O Sodiun Tongba Award Fun Soye Koribee

Ore Karimi Sha Niyen Tio Ni Lada
Tiwon Bawa Sodo E Tonbere Ore
Bo Won Lashiri Koma Tuwon Saye

Toba K′owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Haa, Iwo Iyawo Oloro To M'aye Le Tunko
Aya Shekere Olowo Ilu Tawon Aye Nwi
Iwo Nboko E Ja Pe Kiwon To Nawo
Po Gbodo Ma Sinibe Kotole Tore

Boya O Jebi Bio Basi Jebi Wani No O
Toko E Batun Gbiyanju Kole Tore Gan
Waso Wiponpoju Poti Bawon Je
Abi Ko Kosi Lokan Pe Kole Kere

Abi Kotun Magba Pe Kole Tore Gan
Teyan Bawa Boko E Tonbere Ore
Lo′pore Fawon Alaini Mabolaje

Toba K'owokan Adan Afi Rogi
Eni Tokuniku Sha Lanba Jaye
Teyan Bawa Sodo E Tonbere Ore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore
Dunwon Ninu Allahu Sha Nio Sesan Fun E
Ranwon Lowo Allahu Sha Nio Sesan Oore

Atiya O Ooo, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Atiya O, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Ewo, Seri Gbese Ni Yiya
O Loju Eniyan Tonroju Lati Sanpada Toba Ya
Ayamasan Eda Eyan O, Toba Legberun Nile
Koni San Ogorun Eyi Toya, Toba Sebe Tofiku
Kogba Wipe Ohun Loje
Tawon Ebi E O Balesan
Olohun Ase Esan Fun Ni, Ha, Ayiya

Atiya O, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Ewo, Ofin Olohun Ma Lowipe
Kaka Keniyan O Yawo
O Better Kitoun Toro
Tio Bareni Tolefun, Yawon Tomo Polesan, Kodajo Abigba Tomope

Yio Rorun Latisan, Towo Tóòrokan Bawa De
Ore Malo Gbeshiro Le, Ranti Owo Eyi Toya
Esu Tio Sinbe Tofiya
Aduro Pe Komale San
Iwo Mawobe Koya San
Kole Rimiran Tun Riya Atiya O

Atiya O, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Olohun Ma Mafisewa Aare Tio Gboogun
Todipe Awa Nyawo
Bukata Tao Nile Gbo, Mako Siwa Nigba Mo
O Dokun Lomi Tiogbe, O Dosa Lomi Tio Tan

Owase Makkah Nibiti Lododun Tawon Aye Npeju
Awon Tirue Selesi, Yigba Pada Olola
Eru Re Ma Nbe E O
Shola Tio Niparun Funwa Kamale Dupe Tan Oriyomi Atiya O

Atiya O, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Baba Olowo Ele Erora
Bee Iya, Olowo Ele Erora
Contractor Tio Gbase Ri
Contract Kan Malo Yoju, Nipajawiri Lotunje

Kise Naa Malebo Loje Ko Sato E Wale
Oun Tode Mawi, Onsope Tere Badetan, Fifty Fifty Lemapin, Toun Balo Koreyan Ya
Loba Pada Warie

Owe Toopa Matun Nipe
B'abebe Roke Nigba Igba Ibi Pelebe Ma Naa Ni
Yio Filele O Daju, Igba Tio Nibi Anlomo
Loba Yagba Boseso
Olohun Ni Oun O Fe
Edekun Owo Ele Nyiya Atiya Oriyomi O

Atiya O, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Olowo Oloro Atolola, Tan O Ronu Pawon A Yawo
Adanwo Tan O Ronusi, Lowole Towon Logan
Nonba Deni Tonyawo, Won F′owo Oun Sise
Atoju Owo Pelu Ere O, Ole Ba Jagba Ojilo
Awon Tirue Selesi

Allahu Wa Sanu Funwon
Shiju Aanu Wo Won Kia
Eru Re Ma Unbebe O
Dagba Pada Kon Rina Ha Atiya O

Atiya O, Ati Fun
Atiya O, Ati Fun
Eni Aba Ya Onifokanbale Gbese Nio
Eni Afun A Dabi Eni Jifa Adupe

Bee
Olohun O Gbagbe Ati Soooo-re
Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Soore, Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Sooo Oore
Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Soore, Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Jendupe Nigbeyiiiiiiin O
Jendupe Nigbeyin, Kawon Eyan Wabami Dupe
Allah, Jendupe Nigbeyin
Kawon Eyan Wa Bamidupe

Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Iya O Lowo Baba O Ni, Won Ferawon Won Biwa Sayeeeee
Iya O Lowo Baba O Ni Won Ferawon Won Biwa Saye
Nireti P′aye Ti Eshin Orije Iru Lomaje

Mamase Doju Tiwon Wola Igba Tere Won Doyun
Atife Ton Ni Sirawon, Iwo Lole Bawonse
Jondupe Nigbeyin, Kawon Eyan Wabawon Dupe
Maso Posetan Atise Tiwon, Ma Wowon Niran
Ma Fawon Otawon Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Won Nise Logun Ise Laye O, Sha Lopo Eyan Fin Tepamo
Eyan Tosise Bi Erin Toje Ije Eliri Nikawi
Eni Tojoko Gbowo Wa Nposise Ni Ole

Sungbon Taba Ranti Owe
Kasise Bi Eru, Ko Kuku Da Nkankan
Olohun Lo Ngbeniga Allahu Joo Wasanu Won
Sisesise Laye Konjere Kon Kore Dele, Maso Posetan Atise Tiwon, Ma Wowon Niran
Ma Fawon Otawon Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Olohun Gbenumi Sase Ooooo
Olohun Gbenumi Sase Fawon Eyan Tojomo Nonwa
Konma Sowon Loruko Eyi Ton O Sowon Njo Sunna

Won A Pewon Ni Agan Soruko Eyi Bojumu Ni
Olohun Tosewa Mamasai Wa Rowon Laso

Olohun To Sagbe Mamasai Bawon Ponmisi
Iwo Logbe Ile Omo Dakun Ilahi Wa Fomo Si
Wola Robbana, Atina Fi Duniya Hassnatan Wafil-
Akhirati Hassanatan
Waqinna Adzaba Naar

Je Ondupe Nigbeyiiiin, Allah
Je Ondupe Nigbeyin Kawon Eyan Wabawon Dupe
Ma So Posetan Ati Setiwon, Mawo Won Niran
Ma F'awon Otawon Loro So

Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Olohun Iwo Ma Legbekele Toriwo Lole Bawase
Kaka Ka Besu Lowe Ola Kaya D′opo Olohun Mutan
Eni Raja Ateni Reshin, Talo Jere Ju Ki Ewawi?
Eni Gba Ibeere Mi Toso Idi Toba Fi J'aja

Eyan Toba Mu Eshin Koso Idi Roba Fi Jeshin
Toba Gba Ibeere Miiiiii O
Wa Dupe Nigbeyin

Awon Eyan A Ba E Dupe, Ma Malo Setan Atise Tiwa
Mawowa Niran
Ma Fawon Otawa Loroso

Olohun O Gbagbe Ati Soore
Afi Tio Baya, Maso Posetan Atise Temi
Mawomi Niran O, Ma Fawon Otami Loroso

Allah, Segan Mi Dogo Oo
Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Annabi Ibrahima O, Ko Ko Kahaba Tio
Annabi Sulaimana, Ko Wola Olohun Ti
Yusufu Owa Isho Olohun Tio
Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Annabi Ayuba O, Kowa Alafia Ti
Annabi Musa Kalamu Llah, Ko Gbohun Olohun Ti
Annabi Issa Ruhu-llah, Kojise Olohun Ti
Ma Majen Ware Ayemi Ti O

Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Muhammadu Rosulu Llah
Muhammadu Habiiba Llah
Omo Amina, Muhamma Omo Abudallah
Kojise Olohun Ti Bee, Kowa Ike Olohun Tio

Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Sebi Eyan Shani Mko Moshudi Omo Abiola
Kowola Olohun Ti, Eyan Sha L′eleganza O
Okoya Rasaki, Kowola Olohun Ti

Eyan Shani Folawiyo, Ko Wola Olohun Ti
Bee Kotun Sinlohun Ti, Ma Majen Ware Ayemi Ti O
Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Sebeyan Shani Abidini, Ege Oba L'oando
Eyan Tun Ni Wasiu, Tantala Onipo Ola
Eyan Shani Saidi, Yaro Oba Ni Mobil
Won O Wola Olohun Ti, Ma Maje Nwola Ayemi Tio

Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Eyan Sheu Ismaila, Aderemi T.k
Khalifah Abu Subuanna Llah
Wali Hamdulillah, Alfaa Mini
Ko Wola Olohun Ti Bee Kotun Sinlohun Tio

Segan Mi Dogo
Kepe Ayemi Dire
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Ma Mase Doju Timi Allah Ireni Monwa
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa
Ma Mase Dojutimi Allah Owo Ni Monwa
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa

Ma Mase Doju Timi Allah Ola Ni Monwa
Mase Dojutimi Allah Ire Ni Monwa
 

 
  Oriyomi Kehinde   Writed by Admin  6x     2024-12-23 11:45:32

post a comment